-
Léfítíkù 11:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Gbogbo ohun alààyè tó ń fi àtẹ́lẹsẹ̀ rìn nínú àwọn ohun tó ń fi ẹsẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin rìn yóò jẹ́ aláìmọ́ fún yín. Gbogbo ẹni tó bá fara kan òkú wọn yóò di aláìmọ́ títí di alẹ́.
-