ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 15:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Nígbà ayé Pékà ọba Ísírẹ́lì, Tigilati-pílésà+ ọba Ásíríà kógun wọ Íjónì, Ebẹli-bẹti-máákà,+ Jánóà, Kédéṣì,+ Hásórì, Gílíádì+ àti Gálílì, ìyẹn gbogbo ilẹ̀ Náfútálì,+ ó sì gbà á, ó wá kó àwọn tó ń gbé ibẹ̀ lọ sí ìgbèkùn ní Ásíríà.+

  • 2 Àwọn Ọba 16:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Áhásì wá kó fàdákà àti wúrà tí wọ́n rí ní ilé Jèhófà àti ní àwọn ibi ìṣúra ilé* ọba, ó sì fi àbẹ̀tẹ́lẹ̀ ránṣẹ́ sí ọba Ásíríà.+ 9 Ọba Ásíríà gbọ́ ẹ̀bẹ̀ rẹ̀, ó lọ sí Damásíkù, ó sì gbà á, ó kó àwọn èèyàn inú rẹ̀ lọ sí ìgbèkùn ní Kírì,+ ó sì pa Résínì.+

  • 2 Àwọn Ọba 17:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ní ọdún kẹsàn-án Hóṣéà, ọba Ásíríà gba Samáríà.+ Ó wá kó àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ní ìgbèkùn+ lọ sí Ásíríà, ó sì mú kí wọ́n máa gbé ní Hálà àti ní Hábórì níbi odò Gósánì+ àti ní àwọn ìlú àwọn ará Mídíà.+

  • Àìsáyà 7:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Torí kí ọmọkùnrin náà tó mọ béèyàn ṣe ń kọ ohun búburú, tí á sì yan rere, ilẹ̀ àwọn ọba méjèèjì tí ò ń bẹ̀rù ni wọ́n máa pa tì pátápátá.+

  • Àìsáyà 17:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Damásíkù:+

      “Wò ó! Damásíkù ò ní jẹ́ ìlú mọ́,

      Ó sì máa di àwókù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́