-
Sáàmù 50:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ọlọ́run wa yóò wá, kò sì ní dákẹ́.+
-
-
Jeremáyà 25:32, 33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí:
‘Wò ó! Àjálù kan ń ṣẹlẹ̀ kiri láti orílẹ̀-èdè dé orílẹ̀-èdè,+
A ó sì tú ìjì líle jáde láti ibi tó jìnnà jù lọ láyé.+
33 “‘Àwọn tí Jèhófà máa pa ní ọjọ́ yẹn máa pọ̀ láti ìkángun kan ayé títí dé ìkángun kejì. A ò ní ṣọ̀fọ̀ wọn, a ò ní kó wọn jọ, bẹ́ẹ̀ ni a ò ní sin wọ́n. Wọ́n á dà bí ajílẹ̀ lórí ilẹ̀.’
-