Àìsáyà 1:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Torí àwọn igi ńlá tó wù yín máa tì wọ́n lójú,+Ojú sì máa tì yín torí àwọn ọgbà* tí ẹ yàn.+ Àìsáyà 65:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn èèyàn tó ń fìgbà gbogbo ṣe ohun tó ń bí mi nínú níṣojú mi, +Tí wọ́n ń rúbọ nínú àwọn ọgbà,+ tí wọ́n sì ń mú ẹbọ rú èéfín lórí àwọn bíríkì.
3 Àwọn èèyàn tó ń fìgbà gbogbo ṣe ohun tó ń bí mi nínú níṣojú mi, +Tí wọ́n ń rúbọ nínú àwọn ọgbà,+ tí wọ́n sì ń mú ẹbọ rú èéfín lórí àwọn bíríkì.