Àìsáyà 7:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí náà, Jèhófà fúnra rẹ̀ máa fún yín ní àmì kan: Wò ó! Ọ̀dọ́bìnrin náà* máa lóyún, ó sì máa bí ọmọkùnrin kan,+ ó máa pe orúkọ rẹ̀ ní Ìmánúẹ́lì.*+ Mátíù 1:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 “Wò ó! Wúńdíá náà máa lóyún, ó sì máa bí ọmọkùnrin kan, wọ́n máa pe orúkọ rẹ̀ ní Ìmánúẹ́lì,”+ tó túmọ̀ sí, “Ọlọ́run Wà Pẹ̀lú Wa.”+
14 Torí náà, Jèhófà fúnra rẹ̀ máa fún yín ní àmì kan: Wò ó! Ọ̀dọ́bìnrin náà* máa lóyún, ó sì máa bí ọmọkùnrin kan,+ ó máa pe orúkọ rẹ̀ ní Ìmánúẹ́lì.*+
23 “Wò ó! Wúńdíá náà máa lóyún, ó sì máa bí ọmọkùnrin kan, wọ́n máa pe orúkọ rẹ̀ ní Ìmánúẹ́lì,”+ tó túmọ̀ sí, “Ọlọ́run Wà Pẹ̀lú Wa.”+