Diutarónómì 32:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Torí inú àjàrà Sódómù ni àjàrà wọn ti wá Àti látinú ilẹ̀ onípele Gòmórà.+ Àwọn èso àjàrà onímájèlé ni èso àjàrà wọn,Àwọn òṣùṣù wọn korò.+ Júùdù 7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Lọ́nà kan náà, Sódómù àti Gòmórà àti àwọn ìlú tó yí wọn ká ṣe ìṣekúṣe* tó burú jáì, wọ́n ṣe ìfẹ́ tara tí kò bá ìwà ẹ̀dá mu.+ Ìdájọ́ ìparun* ayérayé tí wọ́n gbà jẹ́ àpẹẹrẹ láti kìlọ̀ fún wa.+
32 Torí inú àjàrà Sódómù ni àjàrà wọn ti wá Àti látinú ilẹ̀ onípele Gòmórà.+ Àwọn èso àjàrà onímájèlé ni èso àjàrà wọn,Àwọn òṣùṣù wọn korò.+
7 Lọ́nà kan náà, Sódómù àti Gòmórà àti àwọn ìlú tó yí wọn ká ṣe ìṣekúṣe* tó burú jáì, wọ́n ṣe ìfẹ́ tara tí kò bá ìwà ẹ̀dá mu.+ Ìdájọ́ ìparun* ayérayé tí wọ́n gbà jẹ́ àpẹẹrẹ láti kìlọ̀ fún wa.+