ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Émọ́sì 2:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Wọ́n tẹ orí àwọn ẹni rírẹlẹ̀ mọ́ eruku ilẹ̀,+

      Wọ́n sì dí ọ̀nà àwọn oníwà pẹ̀lẹ́.+

      Ọkùnrin kan àti bàbá rẹ̀ bá ọmọbìnrin kan náà ní àṣepọ̀,

      Wọ́n sì ń sọ orúkọ mímọ́ mi di aláìmọ́.

       8 Orí àwọn ẹ̀wù tí wọ́n gbà láti fi ṣe ìdúró*+ ni wọ́n ń sùn gbalaja sí lẹ́gbẹ̀ẹ́ gbogbo pẹpẹ;+

      Owó ìtanràn tí wọ́n gbà ni wọ́n fi ra wáìnì tí wọ́n ń mu ní ilé* àwọn ọlọ́run wọn.’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́