Diutarónómì 27:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá ṣe èrú nínú ẹjọ́+ àjèjì, ọmọ aláìníbaba* tàbí opó.’+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’) Jémíìsì 1:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ìjọsìn* tó mọ́, tí kò sì ní ẹ̀gbin lójú Ọlọ́run àti Baba wa nìyí: láti máa bójú tó àwọn ọmọ aláìlóbìí+ àti àwọn opó+ nínú ìpọ́njú wọn,+ ká sì máa pa ara wa mọ́ láìní àbààwọ́n nínú ayé.+
19 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá ṣe èrú nínú ẹjọ́+ àjèjì, ọmọ aláìníbaba* tàbí opó.’+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)
27 Ìjọsìn* tó mọ́, tí kò sì ní ẹ̀gbin lójú Ọlọ́run àti Baba wa nìyí: láti máa bójú tó àwọn ọmọ aláìlóbìí+ àti àwọn opó+ nínú ìpọ́njú wọn,+ ká sì máa pa ara wa mọ́ láìní àbààwọ́n nínú ayé.+