Émọ́sì 6:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ẹ ré kọjá sí Kálínè, kí ẹ sì wò. Ẹ ti ibẹ̀ lọ sí Hámátì Ńlá,+Kí ẹ sì lọ sí Gátì ti àwọn Filísínì. Ṣé wọ́n sàn ju àwọn ìjọba yìí,*Tàbí ṣé ilẹ̀ wọn tóbi ju tiyín lọ ni?
2 Ẹ ré kọjá sí Kálínè, kí ẹ sì wò. Ẹ ti ibẹ̀ lọ sí Hámátì Ńlá,+Kí ẹ sì lọ sí Gátì ti àwọn Filísínì. Ṣé wọ́n sàn ju àwọn ìjọba yìí,*Tàbí ṣé ilẹ̀ wọn tóbi ju tiyín lọ ni?