ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 9:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Gbogbo bàtà tó ń kilẹ̀ bó ṣe ń lọ

      Àti gbogbo aṣọ tí wọ́n rì bọnú ẹ̀jẹ̀

      Ló máa di ohun tí wọ́n fi ń dá iná.

  • Àìsáyà 30:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Wò ó! Orúkọ Jèhófà ń bọ̀ láti ọ̀nà jíjìn,

      Inú ń bí i gan-an, ó sì ń bọ̀ pẹ̀lú àwọsánmà* tó ṣú bolẹ̀.

      Ìbínú kún ètè rẹ̀,

      Ahọ́n rẹ̀ sì dà bí iná tó ń jẹni run.+

  • Àìsáyà 31:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ará Ásíríà máa tipa idà tí kì í ṣe ti èèyàn ṣubú;

      Idà tí kì í ṣe ti aráyé ló sì máa jẹ ẹ́ run.+

      Ó máa sá lọ nítorí idà,

      Wọ́n sì máa fipá kó àwọn ọ̀dọ́kùnrin rẹ̀ ṣiṣẹ́.

       9 Àpáta rẹ̀ máa kọjá lọ torí ìbẹ̀rù tó bò ó,

      Jìnnìjìnnì sì máa bá àwọn ìjòyè rẹ̀ torí òpó tí a fi ṣe àmì,” ni Jèhófà wí,

      Ẹni tí ìmọ́lẹ̀* rẹ̀ wà ní Síónì, tí iná ìléru rẹ̀ sì wà ní Jerúsálẹ́mù.

  • Náhúmù 1:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Ta ló lè dúró nígbà tó bá ń bínú?+

      Ta ló sì lè fara da ooru ìbínú rẹ̀?+

      Yóò tú ìbínú rẹ̀ jáde bí iná,

      Àwọn àpáta á sì fọ́ sí wẹ́wẹ́ nítorí rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́