ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 32:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Lẹ́yìn náà, Jèhófà rán áńgẹ́lì kan, ó sì pa gbogbo jagunjagun tó lákíkanjú + àti àwọn aṣáájú pẹ̀lú àwọn olórí nínú ibùdó ọba Ásíríà, tó fi di pé ìtìjú ló fi pa dà lọ sí ilẹ̀ rẹ̀. Nígbà tó yá, ó wọ ilé* ọlọ́run rẹ̀, ibẹ̀ ni àwọn kan lára àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì ti fi idà pa á.+

  • Àìsáyà 30:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Gbogbo bó ṣe ń fi ọ̀pá rẹ̀ tó fi ń jẹni níyà,

      Èyí tí Jèhófà máa mú wá sórí Ásíríà,

      Máa jẹ́ pẹ̀lú àwọn ìlù tanboríìnì àti háàpù,+

      Bó ṣe ń fi ọwọ́ rẹ̀ sí wọn lójú ogun.+

  • Náhúmù 3:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Gbogbo ẹni tó bá rí ọ máa sá kúrò lọ́dọ̀ rẹ,+ á sì sọ pé,

      ‘Nínéfè ti di ahoro!

      Ta ló máa bá a kẹ́dùn?’

      Ibo ni màá ti rí àwọn olùtùnú fún ọ?

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́