ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 132:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Jèhófà ti búra fún Dáfídì,

      Ó dájú pé kò ní ṣàìmú ọ̀rọ̀ rẹ̀ ṣẹ pé:

      “Ọ̀kan lára ọmọ* rẹ

      Ni màá gbé gorí ìtẹ́ rẹ.+

  • Àìsáyà 53:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Ó máa jáde wá bí ẹ̀ka igi+ níwájú rẹ̀,* bíi gbòǹgbò látinú ilẹ̀ tó gbẹ táútáú.

      Ìrísí rẹ̀ kò buyì kún un, kò sì rẹwà rárá;+

      Tí a bá sì rí i, ìrísí rẹ̀ kò fà wá sún mọ́ ọn.*

  • Ìfihàn 5:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Àmọ́ ọ̀kan lára àwọn àgbààgbà náà sọ fún mi pé: “Má sunkún mọ́. Wò ó! Kìnnìún ẹ̀yà Júdà,+ gbòǹgbò+ Dáfídì,+ ti ṣẹ́gun+ kó lè ṣí àkájọ ìwé náà àti èdìdì méje rẹ̀.”

  • Ìfihàn 22:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 “‘Èmi Jésù rán áńgẹ́lì mi láti jẹ́rìí àwọn nǹkan yìí fún ọ nítorí àwọn ìjọ. Èmi ni gbòǹgbò àti ọmọ Dáfídì+ àti ìràwọ̀ òwúrọ̀ tó mọ́lẹ̀ rekete.’”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́