2 Tẹsalóníkà 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lẹ́yìn náà, a ó fi arúfin náà hàn, ẹni tí Jésù Olúwa máa fi ẹ̀mí ẹnu rẹ̀ pa,+ tí á sì sọ di asán nígbà tó bá ṣe kedere+ pé ó ti wà níhìn-ín.
8 Lẹ́yìn náà, a ó fi arúfin náà hàn, ẹni tí Jésù Olúwa máa fi ẹ̀mí ẹnu rẹ̀ pa,+ tí á sì sọ di asán nígbà tó bá ṣe kedere+ pé ó ti wà níhìn-ín.