Róòmù 15:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àìsáyà tún sọ pé: “Gbòǹgbò Jésè yóò wà,+ ẹni tó máa dìde láti ṣàkóso àwọn orílẹ̀-èdè;+ òun ni àwọn orílẹ̀-èdè yóò ní ìrètí nínú rẹ̀.”+ Ìfihàn 22:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “‘Èmi Jésù rán áńgẹ́lì mi láti jẹ́rìí àwọn nǹkan yìí fún ọ nítorí àwọn ìjọ. Èmi ni gbòǹgbò àti ọmọ Dáfídì+ àti ìràwọ̀ òwúrọ̀ tó mọ́lẹ̀ rekete.’”+
12 Àìsáyà tún sọ pé: “Gbòǹgbò Jésè yóò wà,+ ẹni tó máa dìde láti ṣàkóso àwọn orílẹ̀-èdè;+ òun ni àwọn orílẹ̀-èdè yóò ní ìrètí nínú rẹ̀.”+
16 “‘Èmi Jésù rán áńgẹ́lì mi láti jẹ́rìí àwọn nǹkan yìí fún ọ nítorí àwọn ìjọ. Èmi ni gbòǹgbò àti ọmọ Dáfídì+ àti ìràwọ̀ òwúrọ̀ tó mọ́lẹ̀ rekete.’”+