Ìṣe 11:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nígbà tí wọ́n gbọ́ àwọn nǹkan yìí, wọn ò ta kò ó mọ́,* wọ́n sì yin Ọlọ́run lógo, pé: “Tóò, Ọlọ́run ti fún àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè láǹfààní láti ronú pìwà dà kí àwọn náà lè ní ìyè.”+ Ìṣe 28:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Torí náà, ẹ jẹ́ kó yé yín pé, ìgbàlà yìí tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni a ti kéde fún àwọn orílẹ̀-èdè;+ ó dájú pé wọ́n á fetí sí i.”+
18 Nígbà tí wọ́n gbọ́ àwọn nǹkan yìí, wọn ò ta kò ó mọ́,* wọ́n sì yin Ọlọ́run lógo, pé: “Tóò, Ọlọ́run ti fún àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè láǹfààní láti ronú pìwà dà kí àwọn náà lè ní ìyè.”+
28 Torí náà, ẹ jẹ́ kó yé yín pé, ìgbàlà yìí tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni a ti kéde fún àwọn orílẹ̀-èdè;+ ó dájú pé wọ́n á fetí sí i.”+