Jeremáyà 44:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Gbogbo ọkùnrin tí wọ́n mọ̀ pé àwọn ìyàwó wọn ti ń rú ẹbọ sí àwọn ọlọ́run míì àti gbogbo àwọn ìyàwó tí wọ́n wà níbẹ̀, tí wọ́n jẹ́ àwùjọ ńlá àti gbogbo èèyàn tó ń gbé nílẹ̀ Íjíbítì,+ ní Pátírọ́sì,+ dá Jeremáyà lóhùn pé:
15 Gbogbo ọkùnrin tí wọ́n mọ̀ pé àwọn ìyàwó wọn ti ń rú ẹbọ sí àwọn ọlọ́run míì àti gbogbo àwọn ìyàwó tí wọ́n wà níbẹ̀, tí wọ́n jẹ́ àwùjọ ńlá àti gbogbo èèyàn tó ń gbé nílẹ̀ Íjíbítì,+ ní Pátírọ́sì,+ dá Jeremáyà lóhùn pé: