Àìsáyà 25:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Torí ọwọ́ Jèhófà máa wà lórí òkè yìí,+A sì máa tẹ Móábù mọ́lẹ̀ ní àyè rẹ̀+Bíi pòròpórò tí wọ́n tẹ̀ mọ́ inú ajílẹ̀ tí wọ́n kó jọ.
10 Torí ọwọ́ Jèhófà máa wà lórí òkè yìí,+A sì máa tẹ Móábù mọ́lẹ̀ ní àyè rẹ̀+Bíi pòròpórò tí wọ́n tẹ̀ mọ́ inú ajílẹ̀ tí wọ́n kó jọ.