Léfítíkù 23:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Àwọn àjọyọ̀ àtìgbàdégbà+ tó jẹ́ ti Jèhófà tí ẹ máa kéde+ jẹ́ àpéjọ mímọ́. Èyí ni àwọn àjọyọ̀ mi àtìgbàdégbà:
2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Àwọn àjọyọ̀ àtìgbàdégbà+ tó jẹ́ ti Jèhófà tí ẹ máa kéde+ jẹ́ àpéjọ mímọ́. Èyí ni àwọn àjọyọ̀ mi àtìgbàdégbà: