1 Kíróníkà 16:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà,+ ẹ ké pe orúkọ rẹ̀,Ẹ jẹ́ kí àwọn èèyàn mọ àwọn ohun tí ó ṣe!+ Sáàmù 105:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 105 Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà,+ ẹ ké pe orúkọ rẹ̀,Ẹ jẹ́ kí àwọn èèyàn mọ àwọn ohun tí ó ṣe!+ 2 Ẹ kọrin sí i, ẹ fi orin yìn ín,*Ẹ máa ronú lórí* gbogbo àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ̀.+
105 Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà,+ ẹ ké pe orúkọ rẹ̀,Ẹ jẹ́ kí àwọn èèyàn mọ àwọn ohun tí ó ṣe!+ 2 Ẹ kọrin sí i, ẹ fi orin yìn ín,*Ẹ máa ronú lórí* gbogbo àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ̀.+