Jóòbù 9:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó ṣe àgbájọ ìràwọ̀ Ááṣì,* Késílì* àti Kímà,*+Pẹ̀lú àgbájọ ìràwọ̀ apá gúúsù ojú ọ̀run;* Jóòbù 38:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ṣé o lè so àwọn okùn àgbájọ ìràwọ̀ Kímà,*Àbí o lè tú àwọn okùn àgbájọ ìràwọ̀ Késílì?*+ Émọ́sì 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹni tó dá àgbájọ ìràwọ̀ Kímà* àti àgbájọ ìràwọ̀ Késílì,*+Ẹni tó ń sọ òkùnkùn biribiri di ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀,Ẹni tó ń mú kí ọ̀sán ṣókùnkùn bí òru,+Ẹni tó ń wọ́ omi jọ látinú òkunKí ó lè dà á sórí ilẹ̀,+Jèhófà ni orúkọ rẹ̀.
9 Ó ṣe àgbájọ ìràwọ̀ Ááṣì,* Késílì* àti Kímà,*+Pẹ̀lú àgbájọ ìràwọ̀ apá gúúsù ojú ọ̀run;* Jóòbù 38:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ṣé o lè so àwọn okùn àgbájọ ìràwọ̀ Kímà,*Àbí o lè tú àwọn okùn àgbájọ ìràwọ̀ Késílì?*+ Émọ́sì 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹni tó dá àgbájọ ìràwọ̀ Kímà* àti àgbájọ ìràwọ̀ Késílì,*+Ẹni tó ń sọ òkùnkùn biribiri di ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀,Ẹni tó ń mú kí ọ̀sán ṣókùnkùn bí òru,+Ẹni tó ń wọ́ omi jọ látinú òkunKí ó lè dà á sórí ilẹ̀,+Jèhófà ni orúkọ rẹ̀.
8 Ẹni tó dá àgbájọ ìràwọ̀ Kímà* àti àgbájọ ìràwọ̀ Késílì,*+Ẹni tó ń sọ òkùnkùn biribiri di ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀,Ẹni tó ń mú kí ọ̀sán ṣókùnkùn bí òru,+Ẹni tó ń wọ́ omi jọ látinú òkunKí ó lè dà á sórí ilẹ̀,+Jèhófà ni orúkọ rẹ̀.