-
Mátíù 6:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Tí o bá ń gbàdúrà, má sọ ohun kan náà ní àsọtúnsọ, bí àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè ṣe máa ń ṣe, torí wọ́n rò pé àdúrà àwọn máa gbà torí bí wọ́n ṣe ń lo ọ̀rọ̀ púpọ̀.
-