-
Jeremáyà 51:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Nítorí ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, sọ nìyí:
“Ọmọbìnrin Bábílónì dà bí ibi ìpakà.
Ó tó àkókò láti tẹ̀ ẹ́ mọ́lẹ̀ kí o lè ki.
Láìpẹ́ àkókò ìkórè rẹ̀ máa dé.”
-