-
Jeremáyà 48:38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 “‘Lórí gbogbo òrùlé Móábù
Àti ní àwọn gbàgede ìlú rẹ̀,
Kò sí nǹkan míì, àfi ìpohùnréré ẹkún.
Nítorí mo ti fọ́ Móábù
Bí ìṣà tí a sọ nù,’ ni Jèhófà wí.
-