-
Àwọn Onídàájọ́ 11:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Àmọ́ Síhónì kò fọkàn tán Ísírẹ́lì, kò gbà kí wọ́n gba ilẹ̀ rẹ̀ kọjá, torí náà, Síhónì kó gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀ jọ, wọ́n pàgọ́ sí Jáhásì, wọ́n sì bá Ísírẹ́lì jà.+
-