-
Jeremáyà 48:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ìró ẹkún wá láti Hórónáímù,+
Ti ìparun àti ìwópalẹ̀ tó bùáyà.
-
-
Jeremáyà 48:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Bí wọ́n ṣe ń gòkè lọ ní Lúhítì, wọn ò dákẹ́ ẹkún.
Nígbà tí wọ́n sì ń sọ̀ kalẹ̀ láti Hórónáímù, wọ́n ń gbọ́ igbe ìdààmú nítorí àjálù.+
-