-
Jeremáyà 48:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ìtìjú ti bá Móábù, jìnnìjìnnì sì ti bò ó.
Ẹ pohùn réré ẹkún, kí ẹ sì figbe ta.
Ẹ kéde rẹ̀ ní Áánónì+ pé wọ́n ti pa Móábù run.
-