-
Jeremáyà 48:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀nà, kí o sì máa ṣọ́nà, ìwọ tó ń gbé ní Áróérì.+
Béèrè lọ́wọ́ ọkùnrin tó ń sá lọ àti lọ́wọ́ obìnrin tó ń sá àsálà pé, ‘Kí ló ṣẹlẹ̀?’
-