Sáàmù 51:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Fi hísópù wẹ̀ mí mọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ mi, kí n lè mọ́;+Wẹ̀ mí, kí n lè funfun ju yìnyín lọ.+ Àìsáyà 44:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Màá nu àwọn àṣìṣe rẹ kúrò bíi pé mo fi ìkùukùu* nù ún,+Màá sì nu àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ kúrò bíi pé mo fi àwọsánmà tó ṣú bolẹ̀ nù ún. Pa dà sọ́dọ̀ mi, torí màá tún ọ rà.+ Míkà 7:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó tún máa ṣàánú wa;+ ó sì máa pa àwọn àṣìṣe wa rẹ́.* O máa ju gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wọn sí ìsàlẹ̀ òkun.+
22 Màá nu àwọn àṣìṣe rẹ kúrò bíi pé mo fi ìkùukùu* nù ún,+Màá sì nu àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ kúrò bíi pé mo fi àwọsánmà tó ṣú bolẹ̀ nù ún. Pa dà sọ́dọ̀ mi, torí màá tún ọ rà.+