-
Hósíà 10:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ariwo ogun máa sọ láàárín àwọn èèyàn rẹ,
Gbogbo ìlú olódi rẹ á sì pa run,+
Bí ìgbà tí Ṣálímánì pa ilé Áríbélì run,
Ní ọjọ́ ogun tí a fọ́ àwọn ìyá mọ́lẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn ọmọ wọn.
-