ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 25:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Torí náà, mo gba ife náà lọ́wọ́ Jèhófà, mo sì mú kí gbogbo orílẹ̀-èdè tí Jèhófà rán mi sí mu ún:+

  • Jeremáyà 25:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 lẹ́yìn náà, Fáráò ọba Íjíbítì àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, àwọn ìjòyè rẹ̀ àti gbogbo èèyàn rẹ̀+

  • Ìsíkíẹ́lì 29:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Ọmọ èèyàn, yíjú sọ́dọ̀ Fáráò ọba Íjíbítì, kí o sì sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí rẹ̀ àti sórí gbogbo Íjíbítì.+

  • Jóẹ́lì 3:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Àmọ́ Íjíbítì yóò di ahoro,+

      Édómù yóò sì di aginjù tó dá páropáro,+

      Torí bí wọ́n ṣe hùwà ipá sí àwọn ará Júdà,+

      Ilẹ̀ àwọn tí wọ́n ti ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́