Ẹ́kísódù 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà tí kò lè gbé e pa mọ́ mọ́,+ ó mú apẹ̀rẹ̀* kan tí wọ́n fi òrépèté ṣe, ó fi ọ̀dà bítúmẹ́nì dídì àti ọ̀dà bítúmẹ́nì rírọ̀ kùn ún, ó sì gbé ọmọ náà sínú rẹ̀. Ó wá gbé e sáàárín àwọn esùsú* etí odò Náílì.
3 Nígbà tí kò lè gbé e pa mọ́ mọ́,+ ó mú apẹ̀rẹ̀* kan tí wọ́n fi òrépèté ṣe, ó fi ọ̀dà bítúmẹ́nì dídì àti ọ̀dà bítúmẹ́nì rírọ̀ kùn ún, ó sì gbé ọmọ náà sínú rẹ̀. Ó wá gbé e sáàárín àwọn esùsú* etí odò Náílì.