-
Diutarónómì 11:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 “Ilẹ̀ tí ẹ fẹ́ lọ gbà kò dà bí ilẹ̀ Íjíbítì tí ẹ ti jáde wá, níbi tí ẹ ti máa ń fún irúgbìn yín, tí ẹ sì máa ń fi ẹsẹ̀ yín bomi rin ín,* bí ọgbà tí ẹ gbin nǹkan sí.
-