Àìsáyà 44:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Màá mú kí iṣẹ́ àmì àwọn tó ń sọ̀rọ̀ asán* já sí pàbó,Èmi sì ni Ẹni tó ń mú kí àwọn woṣẹ́woṣẹ́ máa ṣe bí òpònú;+Ẹni tó ń da nǹkan rú mọ́ àwọn ọlọ́gbọ́n lójú,Tó sì ń sọ ìmọ̀ wọn di ti òmùgọ̀;+
25 Màá mú kí iṣẹ́ àmì àwọn tó ń sọ̀rọ̀ asán* já sí pàbó,Èmi sì ni Ẹni tó ń mú kí àwọn woṣẹ́woṣẹ́ máa ṣe bí òpònú;+Ẹni tó ń da nǹkan rú mọ́ àwọn ọlọ́gbọ́n lójú,Tó sì ń sọ ìmọ̀ wọn di ti òmùgọ̀;+