Jeremáyà 46:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Sọ ọ́ ní Íjíbítì, sì kéde rẹ̀ ní Mígídólì.+ Kéde rẹ̀ ní Nófì* àti ní Tápánẹ́sì.+ Sọ pé, ‘Ẹ dúró sí àyè yín, kí ẹ sì múra sílẹ̀,Nítorí idà kan máa pani run ní gbogbo àyíká yín. Ìsíkíẹ́lì 30:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Èmi yóò tún pa àwọn òrìṣà ẹ̀gbin* run, màá sì pa àwọn ọlọ́run Nófì*+ tí kò ní láárí run. Kò ní sí ọmọ Íjíbítì tó máa ṣe olórí* mọ́, màá sì mú kí ìbẹ̀rù wà ní ilẹ̀ Íjíbítì.+
14 “Sọ ọ́ ní Íjíbítì, sì kéde rẹ̀ ní Mígídólì.+ Kéde rẹ̀ ní Nófì* àti ní Tápánẹ́sì.+ Sọ pé, ‘Ẹ dúró sí àyè yín, kí ẹ sì múra sílẹ̀,Nítorí idà kan máa pani run ní gbogbo àyíká yín.
13 “Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Èmi yóò tún pa àwọn òrìṣà ẹ̀gbin* run, màá sì pa àwọn ọlọ́run Nófì*+ tí kò ní láárí run. Kò ní sí ọmọ Íjíbítì tó máa ṣe olórí* mọ́, màá sì mú kí ìbẹ̀rù wà ní ilẹ̀ Íjíbítì.+