Àìsáyà 11:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jèhófà máa pín* ibi tí òkun Íjíbítì ti ya wọ ilẹ̀,*+Ó sì máa fi ọwọ́ rẹ̀ lórí Odò.*+ Ó máa fi èémí* rẹ̀ tó ń jó nǹkan gbẹ kọ lu ọ̀gbàrá rẹ̀ méjèèje,*Ó sì máa mú kí àwọn èèyàn fi bàtà wọn rìn kọjá.
15 Jèhófà máa pín* ibi tí òkun Íjíbítì ti ya wọ ilẹ̀,*+Ó sì máa fi ọwọ́ rẹ̀ lórí Odò.*+ Ó máa fi èémí* rẹ̀ tó ń jó nǹkan gbẹ kọ lu ọ̀gbàrá rẹ̀ méjèèje,*Ó sì máa mú kí àwọn èèyàn fi bàtà wọn rìn kọjá.