Jeremáyà 2:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 ‘Tipẹ́tipẹ́ ni mo ti ṣẹ́ àjàgà rẹ sí wẹ́wẹ́+Mo sì já ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ rẹ. Ṣùgbọ́n, o sọ pé: “Mi ò ní sìn ọ́,” Torí pé orí gbogbo òkè àti abẹ́ gbogbo igi tó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀+ Ni o nà gbalaja sí, tí ò ń ṣe iṣẹ́ aṣẹ́wó.+
20 ‘Tipẹ́tipẹ́ ni mo ti ṣẹ́ àjàgà rẹ sí wẹ́wẹ́+Mo sì já ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ rẹ. Ṣùgbọ́n, o sọ pé: “Mi ò ní sìn ọ́,” Torí pé orí gbogbo òkè àti abẹ́ gbogbo igi tó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀+ Ni o nà gbalaja sí, tí ò ń ṣe iṣẹ́ aṣẹ́wó.+