ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 13:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Fetí sílẹ̀! Ọ̀pọ̀ èèyàn wà lórí òkè;

      Ìró wọn dà bí ìró ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èèyàn!

      Fetí sílẹ̀! Ariwo àwọn ìjọba,

      Ti àwọn orílẹ̀-èdè tó kóra jọ!+

      Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ń pe àwọn ọmọ ogun jọ.+

  • Àìsáyà 13:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ọfà wọn máa run àwọn ọ̀dọ́kùnrin túútúú;+

      Wọn ò ní káàánú èso ikùn,

      Wọn ò sì ní ṣàánú àwọn ọmọdé.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́