Hábákúkù 3:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nígbà tí mo gbọ́, jìnnìjìnnì bò mí;*Ohun tí mo gbọ́ sì mú kí ètè mi gbọ̀n pẹ̀pẹ̀. Egungun mi bẹ̀rẹ̀ sí í jẹrà;+Ẹsẹ̀ mi ń gbọ̀n rìrì. Àmọ́ mò ń fara balẹ̀ dúró de ọjọ́ wàhálà,+Torí àwọn tó ń gbógun tì wá ni yóò dé bá.
16 Nígbà tí mo gbọ́, jìnnìjìnnì bò mí;*Ohun tí mo gbọ́ sì mú kí ètè mi gbọ̀n pẹ̀pẹ̀. Egungun mi bẹ̀rẹ̀ sí í jẹrà;+Ẹsẹ̀ mi ń gbọ̀n rìrì. Àmọ́ mò ń fara balẹ̀ dúró de ọjọ́ wàhálà,+Torí àwọn tó ń gbógun tì wá ni yóò dé bá.