ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 25:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Orúkọ àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì nìyí, orúkọ wọn gẹ́gẹ́ bí ìdílé tí wọ́n ti wá: Àkọ́bí Íṣímáẹ́lì ni Nébáótì,+ lẹ́yìn náà ó bí Kídárì,+ Ádíbéélì, Míbúsámù,+

  • Sáàmù 120:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Mo gbé, nítorí mo jẹ́ àjèjì ní Méṣékì!+

      Mò ń gbé láàárín àwọn àgọ́ Kídárì.+

  • Orin Sólómọ́nì 1:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Ẹ̀yin ọmọbìnrin Jerúsálẹ́mù, mo dúdú lóòótọ́, àmọ́ òrékelẹ́wà ni mí,

      Bí àwọn àgọ́ tí wọ́n fi Kídárì ṣe,+ bí àwọn aṣọ àgọ́+ Sólómọ́nì.

  • Àìsáyà 42:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Kí aginjù àti àwọn ìlú rẹ̀ gbé ohùn wọn sókè,+

      Àwọn ìgbèríko tí Kídárì+ ń gbé.

      Kí àwọn tó ń gbé níbi àpáta kígbe ayọ̀;

      Kí wọ́n ké jáde láti orí àwọn òkè.

  • Jeremáyà 49:28
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Sí Kídárì+ àti àwọn ìjọba Hásórì, àwọn tí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì pa run, ohun tí Jèhófà sọ nìyí:

      “Ẹ dìde, ẹ gòkè lọ sí Kídárì,

      Kí ẹ sì pa àwọn ọmọ Ìlà Oòrùn.

  • Ìsíkíẹ́lì 27:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 O gba àwọn Árábù àti gbogbo ìjòyè Kídárì+ síṣẹ́, àwọn tó ń fi ọ̀dọ́ àgùntàn, àgbò àti ewúrẹ́ ṣòwò.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́