- 
	                        
            
            Jóẹ́lì 2:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        ‘Jèhófà, jọ̀ọ́ ṣàánú àwọn èèyàn rẹ; Má ṣe jẹ́ kí àwọn èèyàn fi ogún rẹ ṣẹlẹ́yà, Kó wá di pé àwọn orílẹ̀-èdè á máa jọba lórí wọn, Tí àwọn èèyàn á fi máa sọ pé, “Ibo ni Ọlọ́run wọn wà?”’+ 
 
-