Ìfihàn 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Kọ̀wé sí áńgẹ́lì ìjọ ní Filadéfíà pé: Àwọn ohun tí ẹni tó jẹ́ mímọ́+ sọ nìyí, ẹni tó jẹ́ òótọ́,+ tó ní kọ́kọ́rọ́ Dáfídì,+ ẹni tó ń ṣí, tí ẹnì kankan ò sì lè tì, tó sì ń tì, tí ẹnì kankan ò sì lè ṣí:
7 “Kọ̀wé sí áńgẹ́lì ìjọ ní Filadéfíà pé: Àwọn ohun tí ẹni tó jẹ́ mímọ́+ sọ nìyí, ẹni tó jẹ́ òótọ́,+ tó ní kọ́kọ́rọ́ Dáfídì,+ ẹni tó ń ṣí, tí ẹnì kankan ò sì lè tì, tó sì ń tì, tí ẹnì kankan ò sì lè ṣí: