-
Náhúmù 3:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Àwọn olùṣọ́ àgùntàn rẹ ń tòògbé, ìwọ ọba Ásíríà;
Àwọn èèyàn pàtàkì rẹ wà ní ibùgbé wọn.
Àwọn èèyàn rẹ ti fọ́n ká sórí àwọn òkè,
Kò sì sẹ́ni tó máa kó wọn jọ.+
-