Míkà 3:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn olórí* rẹ̀ ń gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n tó dájọ́,+Àwọn àlùfáà rẹ̀ ń gba owó kí wọ́n tó kọ́ni,+Àwọn wòlíì rẹ̀ ń gba owó* kí wọ́n tó woṣẹ́.+ Síbẹ̀ wọ́n gbára lé Jèhófà,* wọ́n ń sọ pé: “Ṣebí Jèhófà wà pẹ̀lú wa?+ Àjálù kankan ò lè dé bá wa.”+
11 Àwọn olórí* rẹ̀ ń gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ kí wọ́n tó dájọ́,+Àwọn àlùfáà rẹ̀ ń gba owó kí wọ́n tó kọ́ni,+Àwọn wòlíì rẹ̀ ń gba owó* kí wọ́n tó woṣẹ́.+ Síbẹ̀ wọ́n gbára lé Jèhófà,* wọ́n ń sọ pé: “Ṣebí Jèhófà wà pẹ̀lú wa?+ Àjálù kankan ò lè dé bá wa.”+