-
Léfítíkù 26:15, 16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 tí ẹ bá kọ àwọn òfin mi,+ tí ẹ* sì kórìíra àwọn ìdájọ́ mi débi pé ẹ ò pa gbogbo àṣẹ mi mọ́, tí ẹ sì da májẹ̀mú mi,+ 16 èmi, ní tèmi, yóò ṣe nǹkan wọ̀nyí sí yín: màá kó ìdààmú bá yín láti fìyà jẹ yín, màá fi ikọ́ ẹ̀gbẹ àti akọ ibà ṣe yín, yóò mú kí ojú yín di bàìbàì, kí ẹ* sì ṣègbé. Lásán ni ẹ máa fún irúgbìn yín, torí àwọn ọ̀tá yín ni yóò jẹ ẹ́.+
-