Àìsáyà 43:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Má bẹ̀rù, torí mo wà pẹ̀lú rẹ.+ Màá mú ọmọ* rẹ wá láti ìlà oòrùn,Màá sì kó ọ jọ láti ìwọ̀ oòrùn.+