-
Jeremáyà 9:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ká ní mo ní ibi tí àwọn arìnrìn-àjò lè dé sí ní aginjù!
Mi ò bá fi àwọn èèyàn mi sílẹ̀, kí n sì kúrò lọ́dọ̀ wọn,
Nítorí alágbèrè ni gbogbo wọn,+
Àwùjọ àwọn oníbékebèke.
3 Wọ́n tẹ ahọ́n wọn bí ọrun;
Èké ṣíṣe ló gba ilẹ̀ náà kan, kì í ṣe òtítọ́.+
“Wọ́n ń tinú ibi bọ́ sínú ibi,
Wọn ò sì kà mí sí,”+ ni Jèhófà wí.
-