-
Jeremáyà 8:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 “Àwọn tó bá sì ṣẹ́ kù lára ìdílé búburú yìí á yan ikú dípò ìyè ní gbogbo ibi tí mo bá fọ́n wọn ká sí,” ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.
-