-
Jeremáyà 48:44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 ‘Ẹnikẹ́ni tó bá ń sá lọ nítorí ìbẹ̀rù á já sínú kòtò,
Pańpẹ́ sì máa mú ẹnikẹ́ni tó bá jáde látinú kòtò.’
‘Nítorí màá jẹ́ kí ọdún ìyà Móábù dé bá a,’ ni Jèhófà wí.
-