Ìfihàn 21:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ìlú náà ò nílò kí oòrùn tàbí òṣùpá tàn sórí rẹ̀, torí ògo Ọlọ́run mú kó mọ́lẹ̀ rekete,+ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà sì ni fìtílà rẹ̀.+
23 Ìlú náà ò nílò kí oòrùn tàbí òṣùpá tàn sórí rẹ̀, torí ògo Ọlọ́run mú kó mọ́lẹ̀ rekete,+ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà sì ni fìtílà rẹ̀.+