Sáàmù 91:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 91 Ẹni tó bá ń gbé ibi ìkọ̀kọ̀ Ẹni Gíga Jù Lọ+Yóò máa gbé lábẹ́ òjìji Olódùmarè.+ Sáàmù 121:5-7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà ń ṣọ́ ọ. Jèhófà ni ibòji+ tó wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ.+ 6 Oòrùn kò ní pa ọ́ lára ní ọ̀sán,+Tàbí òṣùpá ní òru.+ 7 Jèhófà yóò máa ṣọ́ ọ kí jàǹbá kankan má ṣe ọ́.+ Yóò máa ṣọ́ ẹ̀mí* rẹ.+ Àìsáyà 49:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ebi ò ní pa wọ́n, òùngbẹ ò sì ní gbẹ wọ́n,+Ooru tó ń jóni ò ní mú wọn, oòrùn ò sì ní pa wọ́n.+ Torí pé Ẹni tó ń ṣàánú wọn máa darí wọn,+Ó sì máa mú wọn gba ibi àwọn ìsun omi.+
5 Jèhófà ń ṣọ́ ọ. Jèhófà ni ibòji+ tó wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ.+ 6 Oòrùn kò ní pa ọ́ lára ní ọ̀sán,+Tàbí òṣùpá ní òru.+ 7 Jèhófà yóò máa ṣọ́ ọ kí jàǹbá kankan má ṣe ọ́.+ Yóò máa ṣọ́ ẹ̀mí* rẹ.+
10 Ebi ò ní pa wọ́n, òùngbẹ ò sì ní gbẹ wọ́n,+Ooru tó ń jóni ò ní mú wọn, oòrùn ò sì ní pa wọ́n.+ Torí pé Ẹni tó ń ṣàánú wọn máa darí wọn,+Ó sì máa mú wọn gba ibi àwọn ìsun omi.+